CCC Inspirational Articles, Download Mp3 Hymns & Songs, Search & Submit Parishes Worldwide & Lots More...

Forums: News Update | Gospel Articles | Constitution/Doctrine | Hymns/Songs | Events | Relationship | Student Fellowships/Parishes

You need to log in to create posts and topics.

Complete version of Ojo Agbara na(Lyrics)

1. Ojo agbara na ti osan d'oru
Ta so jo mimo kale
Irawo meje lo yo ni oke orun
Awon eye IWO n ke luli
CHR: AWON EYE IWO N KE LULI
LULI ORE OFE
IRAWO MEJE LOYO NI OKE ORUN
AWON EYE IWO NKE LULI


2. Osu kesan ojo kankan di logbon
Odun 1947
Ni eyi sele lagogo meta osan
Towo SBJ oshoffa
CHR: EYI L'OKO IKEHIN
TO SOKALE LAT'ORUN
IYE IYE IYE LOHUN NA NKE
SI IJO MIMO CELESTIAL


3. Ise l'ohun na nke e mura sise
Sise pelu ife mimo
Ere ise re ni iwo yio gba
Sise pelu ife mimo
CHR: E JE KA MURA SISE
SISE PELU IFE MIMO
ERE ISE RE NI IWO YIO GBA
SISE PELU IFE MIMO.


4. Eje k'ero yin le ma je ti emi
Ninu emi niye wa
Nitoripe ero ara ohun ni oku
Ninu emi n'iye wa
CHR: NINU EMI N'IYE WA(2X)
NITORIPE ERO ARA OHUN NI OKU
NINU EMI N'IYE WA.


5. Iru ara ota l'oje s'olorun
Idunnu olorun ni emi
Iye enia to gba jesu l'oluwa
Eje ka sin ninu ife
CHR: EJE KA SIN NINU IFE
EJE KA JE SOWOPO
IYE ENIA TO GBA JESU L'OLUWA
EJE KA SIN NINU IFE.


6. Ife l'ohun na nke eje ka lo ife
Gegebi iwe mimo ti wi
Korinti kinni ori ketala
Ife l'ohun na ko wa
CHR: BEERE LATI ESE KINNI
TITI DE IPARI RE
KORINTI KINNI ORI KETALA
IFE LOHUN NA KO WA


7. Igbagbo ni daniloju ohun ti a nreti
Ileri ohun ti a kori
Oniyemeji ki yio ri ohun k'ohun gba
Jesu kristi to fun wa
CHR: ENI TO BA NI JESU
OHUN LO BORI AIYE
ONIYEMEJI KI YIO RI OHUN K'OHUN GBA
JESU KRISTI TO FUN WA.


8. Eje ka toro agbara isin dopin
Ibeere ko lo nise
Kawa le r'ade iye ti o ti pese
Sile fun ijo mimo
CHR: IBEERE KO LO N'ISE
BI KO SE O SE DOPIN
EJE KA SISE KA LE DE ADE OGO
TA PESE FUN IJO MIMO

To download the mp3

visit: https://meetccc.com/mdocs-posts/ccc-song-ojo-agbara-na-ti-osan-doru/

CCC Inspirational Articles, Download Mp3 Hymns & Songs, Search & Submit Parishes Worldwide & Lots More...

Forums: News Update | Gospel Articles | Constitution/Doctrine | Hymns/Songs | Events | Relationship | Student Fellowships/Parishes

WhatsApp Us whatsapp

Click to Share MeetCCC Features To WhatsApp Friends